Tolulope Emmanuel, Osogbo
Ajalu nla lo ja lu awon oloja Oluode nilu Osogbo nidaji oni nigba ti ijamba moto gbemi awon akeegbe won marun.
Elubo isu la gbo pe awon eeyan ohun loo ra ti won fi pade iku ojijji naa labule Arolu nipinle Oyo lasiko ti won n pada bo silu Osogbo.
A gbo pe oloja marun, dereba oko naa pelu kondokito ni won gbemi mi loju ese nigba ti opolopo si farapa.
Ileewosan St Fatimoh Catholic lorita Jaleyemi nilu Osogbo ni won ko awon ti won farapa lo
Olorun amu awon tofarapa larada, aoni ri iru ijamba bemo
ReplyDelete