IROYIN YAJOYAJO

Monday, 23 October 2017

O ma se o! Osere tiata nni, Funke, bimo tan, lo ba ku


Tolulope Emmanuel, Osogbo

Inu ofo nla lawon osere tiata orileede yii wa bayii pelu bi iku se wole were, to si mu okan lara won lo.

Funke Alhassan Abisogun la gbo pe o bimo tuntun lose to koja, ti gbogbo awon osere akeegbe re si n kii ku ewu.

Sugbon ana, ojoo Sande ni iroyin naa kan won lara pe omobinrin to ko fiimu Ajofeebo ati Olowosilee naa ti jade laye.


No comments:

Post a Comment