Tolulope Emmanuel, Osogbo
Ese ko gba ero nileetura Riverside to wa nilu Iwo lojoo Sannde ojo kejilelogun osu yii nibi ayeye ojoobi aadota odun Ogbeni Semiu Okanlawon, eni to je oludamoran pataki fun Gomina Aregbesola lori eto iroyin.
Nibi eto naa la ti ri Gomina Aregbesola, Otunba Gani Adams to je Aare ona kakanfo fun ile Yoruba, Alhaji Gboyega Oyetola to je olori osise loofiisi gomina, awon eeyan nlanla latipinle Eko, awon oloselu latipinle Osun, awon omobibi ilu Iwo kaakiri orileede yii ati bee bee lo.
No comments:
Post a Comment