Afi bii igba ti awon osere tiata ba fee side ere ni Seneto Dino Melaye to wa latipinle Kogi se se niwaju awon akeegbe re ti won wa nile igbimo asofin agba ile wa.
Se ni Melaye figbe bonu pe ti awon asofin naa ko ba fee maa karoyin buruku nipa awon osise ijoba ipinle Kogi, won gbodo tete dide ran won lowo.
O ni alubami ni ebi n lu awon osise ipinle naa latari bi Gomina Yahaya Bello se kuna lati sanwo osu fun won eleyii to ni o wa lara bi okan lara awon osise ohun se gbemi araa re laipe yii.
Leyin atotonu Melaye lawon asofin ohun bere sii dide leyokookan, ti won si n so nnkan ti won yoo fi ran awon osise ohun lowo.
Apo iresi to le ni egberun kan ati igba ni won ri kojo, eleyii ti won yoo lo pin fawon osise ipinle naa laipe.
Bayii ni akosile awon baagi iresi ti won ri ko jo:
Ike Ekweremadu 100
Ahmed Lawan 30
Senators Philip Aduda. 30
Tayo Alasoadura 20
Obinna Ogba 20
Bala Na’Allah 20
Ibrahim Gobir 50
Atai Aidoko Ali and Peter Nwaoboshi 70
Suleiman Adokwe 10
Ben Bruce 10
Jerry Useni 20
Isa Shuaibu 40
Ahmed Ogembe 30
Albert Bassey 20
Mustapha Bukar 20
Yusuf A. Yusuf 15
Baba Kaka Bashir 20
Umaru Kurfi 20
Adamu Aliero 50
Danjuma Goje 50
Bayero Nafada 30
Sam Anyanwu 20
Buruji Kashamu 50
Laah Danjuma 15
Rose Oko 20
Fatima Raji Rasaki 10
Abdullahi Ginmel 20
Ali Wakili 20
Ovie Omo-Agege 5
Barau Jibril 10
Adeola Solomon 20
Rafiu Ibrahim 30
Stella Oduah 30
Sonni Ogbuoji 10
Shaaba Lafiaji 20
Francis Alimekhena 20
Matthew Urhoghide 20
Biodun Olujimi 20
Owoloye omotayo seleri lati gbe baagi iresi egberun kan sile.
No comments:
Post a Comment