IROYIN YAJOYAJO

Monday, 30 October 2017

Ota ilosiwaju nikan ni ko nii ri ohun meremere tijoba Aregbesola ti se l'Osun- Olojudo



Tolulope Emmanuel, Osogbo

Olojudo ti Ido Osun, Oba Adeen Adedapo Sapoyoro ti so pe idagbasoke ti ko lafiwe lo ti ba ipinle Osun laarin odun meje ti Gomina Aregbesola ti dori aleefa.

Lasiko ti Olojudo ko awon ijoye re lo sabewo sodo gomina lo ti sapejuwe isejoba Aregbesola gege bii ohun ti ijoba tiwantiwa duro fun gan an.

Oba yii ni eni to ba feran nnkan rere yoo mo pe Aregbesola yen lati gboriyin fun nitori awon akanse ise to n se kaakiri korokondu nipinle Osun.

Oba yii waa dupe pe gomina ronu ohun rere kan won nilu Ido Osun pelu gbigbe papako ofurufu ti MKO Abiola lo sibe.

Ninu oro ti Aregbesola, o ni oun ko nii kaare lati maa mu ereje ijoba tiwantiwa ba awob eeyan ipjnle Osun nitori pe ileri ti oun se peluu won ni.

No comments:

Post a Comment