Tolulope Emmanuel, Osogbo
Bi eto idibo gomina ipinle Osun se ku odun kan ati ojo merindinlogun bayii, opolopo awon oloselu ni won ti n gbaradi lati gba ipo naa lowo Gomina Aregbesola, sugbon ori ti yoo de ade naa lenikeni ko tii mo.
Die lara awon to see se ki won fife han si ipo ohun nigba ti asiko ba to niyii:
Yio kuku dara, Olorun abawase
ReplyDelete