IROYIN YAJOYAJO

Tuesday, 21 November 2017

Nnkan nla! E wo olopa to n tun ibon se ni soobu jorinmorin


Ibeere to n ti enu gbogbo awon ti won ri foto olopa kan nibi to ti n tun ibon re se ni soobu jorinmorin (welder) kan laipe yii ni pe se nnkan ti le to bayii lorileede wa ni.

Ko seni ti ko mo pe okan lara ohun to se pataki fun eto aabo orileede yii ni ibon tawon olopa wa n gbe lowo, sugbon nigba ti ko ba waa si ibi ipamo kan ti won ti le satunse si ibon to ba baje, nnkan nbe.

Ohun to tun je iberu awon eeyan ni pe to ba je pe ibi gbayau bee ni won ti n tun ibon se, o rorun fawon janduku lati maa gba ibon lowo won laifu won lara.


No comments:

Post a Comment