IROYIN YAJOYAJO

Tuesday, 21 November 2017

Wahala de! Olopa ti Loya mole l'Osogbo, lawon agbejoro ba fariga


Tolulope Emmanuel, Osogbo

Bii oja ni ago olopa to wa lagbegbe Oke-Baale nilu Osogbo ri bayii pelu bi ogunlogo awon agbejoro to wa nilu Osogbo se n wo lo sibe.

Se la gbo pe agbejoro kan lo sibe lati loo gba beeli onibara re kan sugbon a ko mo nnkan to sele ti oga olopa ibe fi pase pe ki won ti agbejoro ohun mole.

A oo mu ohun to fa wahala naa wa fun yin laipe.

No comments:

Post a Comment