![]() |
| Omooba Sikiru Ayedun |
Gege bi ojo ti awon afobaje ilu Ileefe kede re
lati safihan Ooni ti ilu Ileefe tuntun se ku ojo merindinlogun bayii, awon idile
Giesi ti won so pe won leto lati fi oba sile ti bere ayewo finnifinni fawon ti
won ti fife han sipo naa.
Yato si ayewo iwe eri ti won ko sile, won tun sayewo ilera, ojo ori, iriri ati iforowanilenuwo nipa oniruuru ona ti okookan won ti gba lati mu itesiwaju ba ilu Ileefe.
Lara awon ti won ti farahan nibi ayewo naa ni Omooba Sikiru Ayedun, Omooba Adesoji Fadehan, Dokita Rahmon Adedoyin ati bee bee lo.
Sugbon bi idile Giesi se n se eleyii lawon idile Lafogido so pe awon ko lee faramo on ki won tun fowo ola gba awon loju leekansii pelu oniruuru iyanje tawon ti n faramo lateyinwa.
Bee naa ni idile Ademiluyi so pe gboingboin lawon wa leyin idile Lafogido pelu ejo ti won pe sile ejo nitori pe idile kansoso ni ile Giesi, Osinkola ati Ogboru.
Gege bi agbenuso ile Ademiluyi to je eka kan labee Lafogido, Dokita Adenekan Ademiluyi se wi, lasiko ijoba Oba Adesoji Aderemi ni enikeni too gbo oruko awon idile meteeta naa ri ati pe abo igbimo Onidajo Adewale Babalakin lori ipo nilu Ileefe ti odun 1994 ti regi mo won leyin.
O ni ko kan tie bojumu fun enikeni lati ba idile Lafogido du oye naa rara, o si je iwa iyanje fun enikeni lati so pe ipo naa ko to sidile ohun lasiko yii, idi niyii to fi ni awon yoo duro ti ejo to wa nile ejo naa titi ti won yoo fi gba eto won.
Lara awon ti won ti jade latidile Ademiluyi bayii ni Omooba Ademola Ademiluyi; Omooba (Dr) Adefemi Ademiluyi; Omooba Abiodun Adekoyejo Ademiluyi; Omooba Adeyinka Ademiluyi; Omooba Adebowale Ademiluyi; Omooba Adekunle Ademiluyi; Omooba Adetunmbi Ademiluyi; Omooba Adebambo Ademiluyi ati Omooba Adeniyi Ademiluyi.
Latidile Lafogido la ti ri Omowe Charles Adedokun Adesanmi ti gboole Okiti nilu Ileefe atawon miin.
Amo sa, awon akeko ile eko giga ti won je omobibi ilu Ileefe, National Ife Descendants Students' Association (NIDSA) ti so pe gbigbe ejo lo si kootu lori eni ti yoo je Ooni tuntun je eyi ti ko bojumu rara tori pe ipo naa je eyi to lola ati iyi kaakiri agbaye.
Gege bi aare apapo egbe naa, Famakin Olawole se so, oro ipo Ooni koja ife inu enikeni bikose ohn ti ifa ba so gan an ati pe enikeni to ba n gbero lati di ipo naa mu gbodo lee kesebo bata ti Oba Okunade Sijuwade bo sile ko too waja.
Won waa ro gbogbo awon toro kan lati rii pe alaafia joba laisi ikunsinu nibikibi lasiko ati leyin ti wonba kede oruko eni ti ifa yoo yan sori ipo naa.

E tete loo kaa ninu ALAROYE

No comments:
Post a Comment