IROYIN YAJOYAJO

Wednesday, 30 September 2015

Senato Adeyeye di akojanu omo-ile to poju

Awon asofin agba orileede yii ti kede Ojogbon Olusola Adeyeye gege bii olori akojanu ile fun awon omo-ile to poju.
Aare ile, Senato Bukola Saraki lo sekede naa lasiko to n ka leta ti awon asofin lati Ila-Oorun Guusu orileede yii fi sowo sii.
Ninuu leta naa ni won ti so pe Ojogbon Adeyeye to n soju awon eeyan Aaringbungbun ipinle Osun lawon mu.

No comments:

Post a Comment