Ajo to n gbogun ti oniruuru iwa ibaje lorileede Naijiria, The Independent Corrupt Practices and other Related Offences
Commission (ICPC) ti bere iwadi lori isejoba gomina ipinle Osun, Ogbeni Rauf Adesoji Aregbesola.
Eleyii ko seyin leta kan ti egbee Civil Societies Coalition for the Emancipation of Osun State (CSCEO) ko si ajo naa lati fi ejoo gomina, omoo re (Kabiru), die lara awon komisanna to ti ba a sise atawon kan ninu isejoba re sun pe won se obitibiti owo to je tipinle Osun basubasu.
Laipe nireti wa pe ajo naa yoo ranse pe Gomina Aregbesola lati waa wi tenuu re lori awon esun naa, ti alaga ajo CSCEO naa, Comrade Adeniyi Alimi Sulaiman yoo si loo fidi awon esun naa mule nibe.
Sunday, 18 October 2015
Ajo ICPC ti bere iwadi lori isejoba Aregbesola
.Unknown
.
Subscribe to:
Post Comments (Atom)

No comments:
Post a Comment