IROYIN YAJOYAJO

Monday, 19 October 2015

Majiyagbe ni ajo NHRC, ofe si ni isee won

Opolopo ni ko mo pe ti awon olopa ba ti won mole lona aito, ajo kan wa ti won le fejo sun, ti awon yen yoo si gba ise naa se laibeere owo kankan.
Ajo yii ni won n pe ni National Human Rights Commission, odun un 1995 ni won sedasilee re, ojuse ajo yii ni lati dide iranlowo fun enikeni ti won ba fi owo ola gba loju ati lati je olulaja laarin talaka atawon olowo.
Kaakiri ipinle lorileede Naijiria ni oofisi NHRC wa, ki eeyan saa ti lo sibe pelu iwe ehonu tabi ko loo fenu araa re so oun to sele ni, logan ni won yoo muse se, ti won yoo si rii pe iya ko je eni naa gbe.

No comments:

Post a Comment