IROYIN YAJOYAJO

Wednesday, 21 October 2015

Buhari kede Yakubu gege bii alaga ajo INEC

Aare Mohamodu Buhari ti yan Mahmud Yakubu gege bii alaga ajo INEC tuntun forileede yii.
Yakubu gba ipo naa lowo Amina Zakari to n dele de alaga INEC tele latigba ti Attahiru Jega ti gbe ipo naa sile.
Akowe tele fun ajo Tertiary Education Trust Fund ni Yakubu ki won to yan an bayii. Bakan naa ni Aare yan Ogbeni Soyebi Adedeji Solomon gege bii komisanna ajo INEC fun ekun iha Iwo-Oorun Guusu orileede yii.

No comments:

Post a Comment