Leyin odun kan ati ojo mewa ti Kehinde Ide jade laye, ekejii re to je Taiwo naa ti dagbere faye.
Lojoo Sannde to koja la gbo pe Taiwo ti won maa n pe ni Baba Abibat jade laye.
E pade ekunrere nipa iku to pa a
atawon asiri nla miin nipa awon Ibeji Ide yii ninu Akede Agbaye tileese Alaroye n se lojoo Monde to n bo

No comments:
Post a Comment