Egbe oselu APC nipinle Osun ti tako mimu ti Aare Buhari mu Ojogbon Isaac Adewole gege bii minista latipinle Osun.
Gege bi atejade ti alaga Reformer's Group to je egbe odo ninu APC Osun, Comrade Ade Ajayi fi sita, won ni Ipole Ekiti ni baba to bi ojogbon naa ti wa ati pe won kan tedo silu Ilesa ni.
Egbe naa tesiwaju pe bi Adewole ba kan tie je omo ilu Ilesa, ijoba ibile kannaa ti Gomina Aregbesola ti wa loun naa n so pe oun ti wa, eleyii ti won ni ko dun mo awon agbaagba egbe APC l'Osun ninu rara nitori pe Aare Buhari ko fun won lanfaani lati fa eni to wu won sile gege bii minista.
Friday, 16 October 2015
Egbe APC l'Osun so pe Ipole Ekiti ni Adewole ti wa, kii se omo Ilesa
.Unknown
.
Subscribe to:
Post Comments (Atom)

No comments:
Post a Comment