Ile ejo to n gbo esun to suyo leyin idibo gomina to waye lojo kokanla osu kerin nipinle Rivers ti pase atundi ibo nipinle naa eleyii to gbodo waye laarin aadorin ojo.
Won ni idibo gomina naa kun fun magomago ati pe won ko tele awon ilana eto idibo ti ajo INEC gbe kale.
Oludije latinu egbee APC, Dakuku Peterside lo pe Nyesom Wike ti egbe PDP ti ajo eleto idibo kede gege bii eni to jawe olubori ninu idibo naa lejo.
Sugbon Gomina Wike ti gba ile ejoo kotemilorun lo lori idajo naa.
Sunday, 25 October 2015
Ile ejo ni ki won tun ibo gomina ipinle Rivers di
.Unknown
.
Subscribe to:
Post Comments (Atom)

No comments:
Post a Comment