Ooni tuntun fun ilu Ileefe, Enitan Adeyeye Ogunwusi, Ojaja 11 wo ilu Ileefe
ni nnkan aago kan aabo osan oni.
Toll Gate to wa ni Ajebamdele ni awon lobaloba ilu Ileefe ti Lowa ko sodi pelu awon Isoro ti kii kaabo, ti ogunlogo awon eeyan ilu Ileefe si wa nibe lati kii ku oriire.
Wednesday, 28 October 2015
Ooni Adeyeye Enitan Ogunwusi wolu Ileefe tilu-tifon
.Unknown
.
Subscribe to:
Post Comments (Atom)

No comments:
Post a Comment