Agbegbe Gudunbali nipinle Borno niroyin ohun so pe awon omo ogun orileede yii naa ha si, ti iko Boko Haramu si gba opolopo awon nnkan ija alagbara lowoo won.
Sugbon Buratai so pe aheso ti ko lese nile lasan ni ati pe kampe ni gbogbo awon omo ogun orileede yii bii aadojo ti won loo koju awon iko naa wa bayii.

No comments:
Post a Comment