Aare Buhari ti so fun alaga ajo to n gbogun ti awon ti won ba se owo ilu basubasu, iyen EFCC, Ogbeni Ibrahim Lamorde lati bere isinmi ti yoo yori si ifeyinti re lenu ise.
Bee ni aare yan Ogbeni Ibrahim Mustafa Magu, eni to je igbakeji komisanna olopa (ACP) gege bii adele ajo EFCC.
Inu osu keji odun to n bo lo ye ki asiko Lamorde pari.
Monday, 9 November 2015
Buhari fi Magu ropo Lamorde to je alaga ajo EFCC
.Unknown
.
Subscribe to:
Post Comments (Atom)

No comments:
Post a Comment