Leyin odun meji ati osu mesan ti Oluwo ti Iwo nipinle Osun, Oba Ashiru Tadese ti waja, Gomina Aregbesola ti kede yiyan Oluwo tuntun bayii.
Aregbesola fowosi yiyan Omooba Abdulrasheed Akanbi Adewale tidilee Gbaase gege bi Oluwo tuntun.
Onisowo pataki to fi orileede Canada sebujoko ni omooba to le die ni ogoji odun naa, ore pataki ni won si pe oun ati Ooni tuntun, Enitan Ogunwusi.
E ka ekunrere ninu Alaroye ose yii.
Monday, 9 November 2015
Omooba Akanbi Adewale di Oluwo tilu Iwo nipinle Osun
.Unknown
.
Subscribe to:
Post Comments (Atom)

No comments:
Post a Comment