Fun igba karun ninu itan, awon omo egbe agbaboolu orileede Naijiria ti ojo orii won ko tii ju odun metadinlogun lo tun ti gba ife-eye wale.
Ayo meji ni won gba wolee ojugba won latorileede Mali, ti awon yen si n pooyi lorii papa.
Osimhen ati Bamgboye ni won gba ayo mejeeji wole, senken si ni inuu oga won, Amunike n dun si oriire naa.
Monday, 9 November 2015
Golden Eaglet ti gba ife-eye leekarun
.Unknown
.
Subscribe to:
Post Comments (Atom)

No comments:
Post a Comment