Ti ile ejo kotemilorun ba lee gbe idajo tile ejo to n ri si esun to suyo leyin eto idibo gomina nipinle Taraba gbe kale loni ro, Senato Jummai Alhassan ti gbogbo eeyan mo si Mama Taraba ni yoo je obinrin akoko ti yoo di gomina lorileede Naijiria.
Loni ni won dajo pe obinrin yii to dije labe egbe oselu APC lo jawe olubori, ti won si pase pe ki Gomina Darius Ishaku ti egbee PDP fi ipo naa sile.
Sugbon Ishaku ti so pe oun nlo sile ejoo kotemilorun.
No comments:
Post a Comment