IROYIN YAJOYAJO

Wednesday, 4 November 2015

Ileese asobode gbese kuro lori ofin to de iresi kikowole

Oga agba funleese asobode lorileede yii, Col. Hameed Ali ti pase pe ki won yo iresi kuro lara awon ounje tijoba fofin de pe won ko gbodo ko wo orileede Naijiria.
Ali, eni ti alukooro ileese asobode, Ogbeni Wale Adeniyi gbenuso fun salaye pe igbese yii waye lati le je kawon ti won n ko iresi wole maa san owo to to lori awon oja naa, ki won si dekun kiko iresi wole lona ti ko bofinmu.

No comments:

Post a Comment