Ko seni to ri ile naa ti ko nii lanu. Parakin nilu Ileefe la gbo pe Oba Enitan Adeyeye Ogunwusi, Ojaja Keji, tii se Ooni tilu Ileefe ko ile alaranbara naa si.
Bi awon kan se n so pe ose mefa pere lawon osise fi sise tosan-toru nibe, bee lawon miin so pe ose mesan ni. Ju gbogbo re lo, ajanaku nile alawo funfun ohun, o kojaa mo ri nnkan firi.
Friday, 27 November 2015
Won ni ose mefa pere ni Ooni Ogunwusi fi kole awosifila yii
.Unknown
.
Subscribe to:
Post Comments (Atom)

Kaabiesi o
ReplyDelete