Onorebu Samson Oladejo Makinde tii se adari awon omo egbe to kere ju, iyen PDP nile igbimo asofin ipinle Osun ti jade laye loni to ye ko je ojo ayeye ojo-ibi re.
Omobibi ilu Ileefe ni.
E ka ekunrere nipa iku to pa Igwe
ninu Alaroye ti yoo jade lojoo Tusde, ojo kokandinlogbon osu kejila yii.
Sunday, 27 December 2015
Adari omo egbe to kere ju nile igbimo asofin ipinle Osun ti ku
.Unknown
.
Subscribe to:
Post Comments (Atom)

No comments:
Post a Comment