IROYIN YAJOYAJO

Tuesday, 29 December 2015

Femi Adesina padanu egbon e ninu ijamba moto

Adanu nla ni iku Ojogbon Foluke Ogunleye je fun idile oludamoran pataki lori eto iroyin fun Aare Buhari, Ogbeni Femi Adesina pelu bi iku se gbemi e loju ona Ibadan si Eko lojoo Satide, ojo kerindinlogbon osu yii.
Oluko agba ni Ojogbon Ogunleye ni Obafemi Awolowo University, eka ti won ti n ko nipa ere ori itage, iyen Dramatic Art lo wa nigba ayee re.
Omo odun metalelaadota ni Ojogbon Ogunleye to je omobibi ilu Ipetumodu nipinle Osun yii.

No comments:

Post a Comment