IROYIN YAJOYAJO

Saturday, 19 December 2015

Awon Hausa naa ti so pe awon fee ya kuro ninu Naijiria o

Egbe kan ti won pe oruko araa won ni Arewa Youth Forum ti so pe awon naa ti setan lati kuro lara orileede Naijiria.
Gege bi adari egbe naa, Sulaiman Mohammed Sanni se wi, awon naa fe orileede tawon ti won yoo pe ni United State of Arewa Republic gege bi awon eya Igbo kan naa se n pe fun orileede Biafra.

No comments:

Post a Comment