IROYIN YAJOYAJO

Monday, 21 December 2015

Won ni omo ilu Ileefe ni baba to bi Pasuma

Bo tile je pe ilu Oro nipinle Kwara ni gbajumo osere Fuji to tun n se tiata nni, Alhaji Wasiu Alabi Pasuma maa n pe baba e, iwadi ti fihan pe ilu Ileefe nipinle Osun gan an ni baba Ijoba Fuji ti wa.
Alagba Odetola la gbo pe o yera fun Pasuma ati iya re, Alhaja Kuburat Adija Oritooke nitori pe ko faramo ise orin Fuji to n se.
Iya Pasuma lo je omo ilu Oro, omo ilu Ileefe ni baba to bii lomo.

No comments:

Post a Comment