Idunnu subu lu ayo fundile agba oje olorin fujii ni, Wasiu Ayinde Mashal, ti gbogbo eeyan mo si K1 the Ultimate, nigba ti okan lara awon omobinrin re, Damilola Marshal keko gboye gege bii agbejoro lorileede yii.
Yunifasiti North America University Houdegbe, Cotonou lorileede Benin Republic ni Damilola omo odun meedogbon ti jade sugbon orileede yii lo ti keko olodun kan eleyii to so o di agbejoro lojo keedogun osu ti a wa yii.
Damilola lomobinrin keji ti K1 yoo to jade gege bii agbejoro lorileede Naijiria.

No comments:
Post a Comment