Odaju abiyamo kan toruko re n je Esther William lowo ileese olopa ipinle Eko ti te bayii lori esun pe o da omi gbigbona le alabagbele re, Mabel Enwongomfon-Umoh lori.
Omokunrin kan to je aburo enikan to n gbe ninu ile naa la gbo pe o n ba orebinrin re ja lenu ona yara Mabel, nigba ti ariwo won po ni Mabel, to n gbe omo osu meji lowo, jade sita loo fejo sun eni to je anti omokunrin naa, eleyii ti a gbo pe o bi Esther ti oro ko kan rara ninu.
O gbe ija kojuu Mabel, oro si di ija debii wipe oko Mabel lo loo pase funyawo re pe ko kuro lodoo Esther.
Bi won se n lo sinu yaara won pada ni Esther sare wonu ile, o gbe omi gbigbona, o si da le Mabel lori. Gbogbo ara re lo bo, koda ko lanfaani lati fun omo osu meji to n gbe lowo loyan rara.
Bo se fee maa salo bi oko Mabel

No comments:
Post a Comment