Ile ejo kotemilorun ti so pe oludije labe egbe oselu APC ninu idibo gomina to waye nipinle Taraba lojo kokanla osu kerin odun yii, Aisha Alhassan ati egbe oseluu re ko lagbara labe ofin lati pe eto ti egbe oselu PDP fi gbe Gomina Darius Ishaku kale lati dije
nipinle naa lejo.
Ninu idajo ti awon igbimo eleni-marun naa labe alaga won, Onidajo Abdul Aboki gbe kale ni won ti so pe idajo ti ile ejo to n gbo esun to suyo leyin idibo gbe kale lojo keje osu kokanla odun yii, ninu eyi to ti fagile ibo to gbe Ishaku wole lori esun pe ona ti egbe PDP gba fa a kale ko bojumu, ko leto rara, bee niko si si nibamu pelu ofin orileede Naijiria.
Thursday, 31 December 2015
Ile ejo kotemilorun so pe jijawe olubori Darius Ishaku tipinle Taraba bofin mu
.Unknown
.
Subscribe to:
Post Comments (Atom)

No comments:
Post a Comment