IROYIN YAJOYAJO

Friday, 28 October 2016

Ilu Akure daru nitorii Jimoh ati Eyitayo

Wahala n sele lowolowo bayii nilu Akure ti se olu ilu ipinle Ondo latari bi ajo INEC se kede pe Dokita Jimoh Ibrahim ni oludije funpo gomina latinu egbe oselu PDP ti yoo waye ninu osu kokanla odun yii.
Se lawon ololufe Eyitayo Jegede fon sita, ti won si n pariwo pe awon ko fe Ibrahim, bee lawon banki pelu ileetaja gbelekun won ti, ti onikaluku si rora n yoju ninu ile lati wo bi nnkan se n lo.

No comments:

Post a Comment