IROYIN YAJOYAJO

Wednesday, 23 November 2016

Ile ejo kotemilorun to fikale silu Abuja ti kede Eyitayo Jegede gege bii oludije to leto lati dije funpo gomina ipinle Ondo labe asia egbe oselu PDP.
Adajo Saulawa pase pe ki ajo INEC gba iwe ti won fun Jimoh Ibrahim, ki Eyitayo si dije ninu idibo ojoo satide to n bo yii.

No comments:

Post a Comment