Owo ileese olopa ipinle Ogun ti te baba eni odun metalelogoji lori esun pe o n ba awon omokekeke ti won wa laarin odun mesan si mejila lopo.
Ojo ti pe ti Ini ti maa n jeran sunkunsi awon omo meteeta ti won je awon omo alajogbele re ohun ko too di pe asiri re tu laipe yii nigba ti iya okan lara awon omo naa sakiyesi 'ato' okunrin lara awotele re.
Omo yii lo jewo pe nigbakuugba ti Ini ba ti dogbon ran awon nise nigba ti ko ba si awon obi awon pelu Iyawo baba agbaaya yii nile lo maa n ki awon mole ninuu yaara.
Ojule keji ni agboole Agboola ni Sango ipinle Ogun la gbo pe won jo n gbe.
Thursday, 24 August 2017
Agbaaya! Nipinle Ogun, owo te Ini to n se 'kinni' fawon omo kekeke
.Unknown
.
Subscribe to:
Post Comments (Atom)

No comments:
Post a Comment