Latari pe won jiwe wo lasiko ti won joko fun idanwo oniwe mewa WAEC, eeyan mokandinlogbon ti da iwe eri idanwo won pada bayii.
Ajo WAEC lo soro yii lasiko ipade awon igbimo idanwo naa eleekejilelogota iru e.
Won ni awon iwe eri ti won da pada naa je ti odun 1984, 1985, 2000, 2001, 2002, 2005, 2006, 2008 ati ti odun 2012.
Ohun ti awon eeyan ohun so ni pe awon ti di atunbi bayii ati pe awon ko fe nnkan ti ko nii je ki eri okan awon nisinmi.
Thursday, 24 August 2017
Nitori iberu orun apaadi; Eeyan mokandinlogbon da iwe eri WAEC won pada
.Unknown
.
Subscribe to:
Post Comments (Atom)
No comments:
Post a Comment