Latari bi oniruuru iroyin ti ko dun mojoba ninu se maa n fi gbogbo igba jade lori itakun ayelujara, ileese ologun orileede yii ti ni awon yoo bere sii dode enikeni to ba n san iru aso bee soro.
Oga agba fun eto ibaraenisoro nileese ologun orileede yii, Major General John Enenche lo soro yii leyin ti Aare Buhari so pe oniruuru nnkan tawon eeyan nko sori ero ayelujara wa lara wahala torileede yii n dojuko.
Enenche ni ileese ologun ko nii fi owo kekere mu oro naa mo nitori alaafia orileede yii lo je awon logun.
Thursday, 24 August 2017
Home
/
Unlabelled
/
Awada kerikeri! Awon soja fee maa mu enikeni to ba lo itakun ayelujara lati tako ijoba
Awada kerikeri! Awon soja fee maa mu enikeni to ba lo itakun ayelujara lati tako ijoba
.Unknown
.
Subscribe to:
Post Comments (Atom)
No comments:
Post a Comment