IROYIN YAJOYAJO

Wednesday, 23 August 2017

O to ge! Awa o fe arugbo nijoba mo - Kayode Oduoye

Okan lara awon oludije funpo gomina nipinle Osun, Amofin Kayode Oduoye ti so pe ko si anfaani kankan torileede yii ti je latigba tawon agbaagba ti n dari re.
Lasiko to n kopa lori eto orii redio Splash FM lo salaye pe asiko ti to fawon odo lati gbajoba ki itesiwaju le ba orileede yii ni gbogbo ona.
Oduoye, eni to n gbaradi lati dije labe egbe oselu PDP lodun to n bo, o ni ipo egungun gbigbe tijoba to wa l'Osun bayii ko ipinle ohun si lo fa a toun fi pinnu lati dije.

No comments:

Post a Comment