Busayo Adegoke, eni ogbon odun ti pariwo bayii nilu Ileefe pe ki won gba oun lowoo Woli Dayo Olorunayo to je oludasile ijo emi kan nilu Ileefe nitori ojoojumo lo n ponmi si 'jogbo' oun.
Busayo ni latari nnkan osu oun to dede duro ni ore oun, Adeoti fi mu oun lo sodo Woli Olorunayo eni to fun oun ni oogun kan bii omi lati maa mu sugbon ti oun ko mo pe oogun ife lo gbe foun.
O ni latigba toun ti mu kinni naa ni Woli ti n fi gbogbo igba lasepo pelu oun, bee loun si n ru toun n gbe.
Nigba tawon araa Kootu Emese laafin Ooni beere bi oro se je lenuu Woli, o ni loooto loun fun Busayo loogun ife toun si n ba a sun karakara sugbon oun ko mo si bo se n ru to si n gbe.
Awon Emese gboju aagan si iwa Woli naa bee ni won si kilo fun Busayo ati ore re pe ki won yee tojulee Woli kaakiri.
Saturday, 26 August 2017
Home
/
Unlabelled
/
E gba mi o! Iwosan ni mo wa lo sodo Woli Olorunayo, oogun ife lo fun mi, ojoojumo lo n ba le mi lori -Busayo
E gba mi o! Iwosan ni mo wa lo sodo Woli Olorunayo, oogun ife lo fun mi, ojoojumo lo n ba le mi lori -Busayo
.Unknown
.
Subscribe to:
Post Comments (Atom)
No comments:
Post a Comment