IROYIN YAJOYAJO

Thursday, 31 August 2017

Erin wo! Aare ana funjo CAC lagbaye ti jade laye

Agbosogbanu niroyin naa je nigba tawon eeyan gbo pe aare ana fun ijo Christ Apostolic Church, Pastor Elijah Howard Lajuwomi Olusheye ti jade laye.
Baba yii lo je aare karun funjo naa. Olusheye di aare ijo CAC lodun 1997, o si feyinti lodun 2011.
Omo odun mejilelogorin ni Baba Olusheye ko too jade laye.

2 comments:

  1. Ema sun ninu Oluwa Baba tibi tiko tini si ipinya mo

    ReplyDelete
  2. Ema sun ninu Oluwa Baba tibi tiko tini si ipinya mo

    ReplyDelete