Ogbologbo okunrin ajinigbe toruko re gbale-gbona losu kan seyin nigba ti owo ileese olopa ipinle Eko te e, Chukwudi Onwuamadike a.k.a. Evans ti so funle ejo pe oun jebi gbogbo esun ti won fi kan an.
Esun mejilelaadota ni won fi kan Evans atawon isomogbe re, lara awon esun naa ni ipaniyan, ijinigbe, idigunjale ati kiko awon nnkan ija oloro kaakiri.
Nigba ti won ka awon esun naa si Evans leti nile ejo giga ilu Eko, o ni oun jebi won.
A oo ranti pe ni Magodo nipinle Eko lowo ti te Evans latigba naa lo si ti wa lakolo olopa.
Agbejoro re lo sile ejo pe ko leto bawon olopa se tii mole lai gbe lo si kootu, bee ni ile ejo giga apapo pase pe ki won gbe e lo sile ejo.
Opolopo odun lawon olopa fi wa Evans, ogbologbo to ti di bilonia nidi ise ajinigbe ko too di pe owo te e. Latigba naa si lopolopo araalu ti Evans ti sose fun ti n yoju gege bii eleri lori awon esun to n jejo won.
Wednesday, 30 August 2017
'Oluwa mi, mo jebi gbogbo awon esun ti won fi kan mi" - Evans
.Unknown
.
Subscribe to:
Post Comments (Atom)
Of in gbodo side owo e Lori Evans ati awon e gbee.Iwa odaran tipoju Lori lede yi. Ona kasoso Latin dekun iwa odaran niki awon odaran ari awon arufin Latin ma jiya gege botito ati boti ye labe ofin
ReplyDelete