Bo tile je pe ojoojumo nijoba ipinle Osun n so pe awon ko je gbese, atejade kan ti ileese ti won n pe ni National Bureau of statistics gbe jade laipe yii ti fidi re mule pe gbese tipinle Osun je din die ni bilioonu lona eedegbesan naira.
E wo tabili atejade naa :
Subscribe to:
Post Comments (Atom)
Oga O
ReplyDelete