Èyí ni lati kéde ètò ìsìnkú olóògbé Alàgbà Omooba ọ̀mọ̀wé Adébáyọ̀ Mosobálájé Ajíbádé Àkàndé ọmọ Fálétí.
ỌJỌ́ IṢẸ́GUN , 5/9/17:-
Alẹ́ ìgbóríyìn àti òsèré.
Oríkò :-Gbọ̀ngan Apérò Fásítì Ìbàdàn. Àkókò :Aago mẹ́rin ìrọ̀lẹ́.
ỌJỌ́́ RÙ Ú, 6/9/17
Ìsìn fún olóògbé ẹniire :- Oríko : Ìjọ Oníteẹ̀bọmi Salem, Yemetu Ìbàdàn. Àkókò : Aago méjìlá ọ̀sán.
ỌJỌ́ BỌ, 7/9/17
Títẹ́ òkú ní ìtẹ́ ẹ̀yẹ ní ilé olóògbé , àdúgbò Olóròóró, Ọjọ́ọ̀ Ìbàdàn: Àkókò : Aago mẹ́jọ sí mẹ́sàn án ààbọ̀ àárọ̀.
Ìtẹ́ ẹ̀yẹ ní ilé iṣẹ́ ìròyìn BCOS
Àkókò : Aago mẹ́wàá sí mọ́kànlá àárọ̀.
Ite ẹ̀yẹ ní ilé iṣẹ́ ìròyìn NTA Ìbàdàn
Àkókò : Aago mọ́kànlá àárọ̀.
Ìtẹ́ ẹ̀yẹ ní gbọ̀ngan lóyèlóyè,
Àkókò :Aago mọ́kànlá ààbọ̀ àárọ̀.
NÍ ÌLÚ Ọ̀YỌ́ ́ -
Ìsìn àsálẹ́ orin onígbàgbó,
Oríkò : Ìjọ Onítẹ̀bọmi Kínní, Isokun, Ọ̀yọ́.
Àkókò: Aago mẹ́rin.
ÀSÁLẸ́ ÀWỌN ÒSÈRÉ
Oríkò : Plaza de Haruna Hotel, Ọ̀yọ́
Àkókò : Aago mẹ́jọ àṣálẹ́.
ỌJỌ́ ETÌ, 8/9/17 Àṣekágbá ètò ìsìnkú, Oríkò: Ìjọ Onítẹ̀bọmi, Isokun, ọ̀̀̀yọ.
Òkú yóò wọ káà ilẹ̀ sùn ní Abúlé Agboye, Oyo lọ́nà ògbómọ̀ṣọ́.
Wẹ̀jẹ wẹ̀mu àti ijó ẹni ọmọ sìn yóò wáyé ní Lábámba Hotel, Oyo.
ÀBUWỌ́́LÙ
Ayọ̀ọlá Fálétí
fún gbogbo ẹbí.
Tuesday, 5 September 2017
O digbere! Alagba Adebayo Faleti bere irinajo sile ikeyin loni
.Unknown
.
Subscribe to:
Post Comments (Atom)
RIP Baba Oninu rere
ReplyDelete