IROYIN YAJOYAJO

Wednesday, 13 September 2017

Omooba Olagunsoye Oyinlola di alaga NIMC

Gomina tele nipinle Osun, Omooba Olagunsoye Oyinlola ni won ti yan bayii gege bii alaga ajo to n seto kaadi idanimo orileede yii, iyen National Identity Management Commission (NIMC).
Laipe yii ni won kede Oyinlola, eni to je akowe apapo tele fegbe oselu PDP lorileede yii ko too kuro nibe lasiko ti wahala be sile laarin re ati alaga apapo egbe ohun nigba naa, Bamangar Tukur.
Igba akooko niyii ti won yoo yan Omooba Oyinlola to je omobibi ilu Okuku sipo ni gbangba bee latigba to ti darapo mo egbe

No comments:

Post a Comment