IROYIN YAJOYAJO

Saturday, 23 September 2017

Ope oo!! Won ti kede ojo ti won yoo dibo ijoba ibile l'Osun

Arigbamu iroyin to wa larowoto wa bayii ti fidi re mule pe ipari osu kejila odun yii ni gomina ipinle Osun, Ogbeni Rauf Aregbesola ti pinnu lati seto idibo sawon ijoba ibile ogbon ati awon ijoba ibile agbegbe mokanlelogbon to wa nipinle Osun.
Leyin eto idibo yii, gege bi a se gbo, lawon ti won ba nife lati dupo gomina yoo to lanfaani lati sepolongo erongba won fawon araalu.
Sugbon oro to n lo laarin awon omo egbe oselu APC nipinle Osun ni pe eto isejoba ti yoo fun awon araalu lanfaani lati yan alaga atawon kanselo ti won fe sipo lawon n fe.
Won ni awon ko faramo eto eleyii ti Gomina Aregbesola n se lowolowo ninu eyi to je pe awon igbimo kan ni won yoo yan enikan laarin araa won gege bii alaga nijoba ibile kookan.
A oo ranti pe opolopo igba lawon egbe oselu alatako pelu oniruuru awon ajafetoomoniyan ti pariwo, ti won si lo si kootu pe dandan kijoba seto idibo sawon ijoba

2 comments:

  1. Yio dara pupo ki eto idibo naa lo ni iroworose, ki asi gba ife okan awon oludibo laye lati we. Yio dara fun ipinle Osun

    ReplyDelete