Ileese olopa ipinle Ekiti ti bere iwadi lori iku to pa okunrin sorosoro orii redio kan, Alfa Abdulganiyu Lawal, won si ti seleri lati fa awon afookunsika naa jade.
Irole ojoo Tosde to koja la gbo pe okunrin to tun maa n sise ode igbo naa dagbere fawon oree re pe oun yara fee degbe lo ati pe oun yoo pada ko too di aago mewa ale.
Sugbon alo Alfa eni odun mejilelogoji yii ni won ri, won ko ri ipadabo re, bee ni ero ibanisoro re ko lo rara.
Nigba to di aaro ojo keji, awon ebi ati ore re gba ago awon olopa lo ni Ilasa lati fi oro naa to won leti. Bayii ni won bere sii wa okunrin yii.
Ko pe niroyin kan won lara pe oku enikan wa legbe igbo ni Apepe Farm Settlement ni Araromi-Oke.
Gbogbo won sare lo sibe, iyalenu lo si je fun won pe oku Alfa Ganiyu ni won ba nileele pelu oju ogbe ibon laraa re.
Ojo naa ni won si sinku re nilana esin Islam nilee re to wa ni Igbemo-Ekiti. O fi iyawo kan pelu awon omo meta sile saye lo.
Amo sa, ileese olopa ni awari ti obinrin maa n wa nnkan obe lawon yoo fi oro awon ti won pa okunrin ti gbogbo aye royin gege bii oniwatutu ohun se.

No comments:
Post a Comment