IROYIN YAJOYAJO

Wednesday, 1 November 2017

Bamigboye fo igo mo Segun lori, lo ba foju bale ejo



Tolulope Emmanuel, Osogbo

Ifeoluwa Bamigboye, omo odun mokandinlogun lo ti foju bale ejo majistreeti ilu Osogbo lori esun pe o gun Segun Ajibade nigo.

Ojo kerinlelogun osu kewa odun yii la gbo pe o huwa naa ni nnkan aago merin irole lagbegbe Dele Yes-sir nilu Osogbo.

Inspekito Fagboyinbo ni Bamigboye ba opolopo nnkan bii eyin tutu, buredi, omi inu ike ati bee bee lo je lojo naa, apapo owo nnkan to to egberun lona mewa naira.

Adajo majistreeti naa, Adenike Olowolagba gba beeli re pelu egberun lona ogorun naira ati oniduro meji ni iye kannaa.

O waa sun igbejo siwaju di ogunjo osu kejila odun yii.

No comments:

Post a Comment