Lasiko yii ti opolopo awon odobinrin n je gbese repete latari aso ti won fee wo lojo igbeyawo won, iyalenu lo je fun gbogbo awon eeyan agbegbe kan nilu Eko laipe yii nigba ti moto gbe iyawo kan de ti won si rii pe Sutana ijo Celestial lo wo.
Omobinrin yii funfun kinniwin ninu aso naa pelu iboji funfun ati filawa to gbe lowo, bee ni ore iyawo naa ko sinui Sutana.
Okooyawo gan an funra re ko daamu rara, se lo wa Sutana tuntun ran, ti ohun gbogbo si n lo laisiyonu nibi eto naa.
No comments:
Post a Comment