IROYIN YAJOYAJO

Wednesday, 29 November 2017

Odaran ni Matthew yii o ! O si tun fee dogbon gbe igbo wole fawon elewon l'Abeokuta


Owo awon osise ogba ewon ipinle Ogun, iyen Special Intelligence Squad of the Controller General of Prisons, Ogun State Command ti te Matthew Olusi lasiko to n gbiyanju lati gbe 'igbo' wole fawon elewon.
Awotele kan la gbo pe Matthew omo odun mejilelogun yi igbo naa mo, o si ju u sinuu baagi dudu kan.
Nigba to de enu geeti Old Abeokuta prison, nilu Ibara ni won ni ko tu eru owo e, ko koko gba fun won sugbon nigba ti oro naa di ariwo, o tu u, won si ba igbo ohun nibe.
Matthew jewo pe awon ore oun ti won wa ninu ogba ewon lohun fee dogbon gbe igbo naa fun.
Oludari agba logba ewon nipinle Ogun, Abolade Benson ni oun ti fa Matthew le  awon ajo to n gbogunti lilo egboogi oloro lowo.

No comments:

Post a Comment