IROYIN YAJOYAJO

Saturday, 4 November 2017

Olori Badirat Adeyemi sayeye ojobi odun kejidinlogbon, aye gbo, orun mo



Ojo keta osu kokanla odun 1989 ni won bi Olori Badirat Olaitan Ajoke Adeyemi eni tii se olori kekere laafin Oba Adeyemi, Alaafin Keta ti ilu Oyo.

Lati ose die seyin lo ti n sepalemo fun ayeye ayajo ojoobi odun kejidinlogbon to doke eepe.

Alaafin lo koko gbe oko Toyota matrix sports funfun fun Olori Ajoke gege bii ebun ojoobi re.

E wo foto ayajo naa:






No comments:

Post a Comment