IROYIN YAJOYAJO

Saturday, 4 November 2017

Ona kan o w'oja! Wasiu Ayinde si ileese buredi 'Anjola'


Lati le mu ki ona ti owo yoo maa gba wole fun un tun bureke sii, gbajugbaja olorin fuji nni, Alhaji Wasiu Ayinde Omogbolahan ti si ileese to ti fee maa ta buredi bayii.
Oluaye Fuji tabi King of Fuji bi awon ololufe re se maa n pe e ni ko le pa idunnu re mora nigba ti awon ore ati ojulumo re pejo lati baa dawoodunnu ileese Anjola Bread naa.



No comments:

Post a Comment